Layori es una cantante de Nigeria.
Canta en su idioma yoruba.
Esta canción me gusta mucho, pero no la entiendo.
Da da
Layori
Dada la ma dé ibi tan lo
Pelu ayo la ma dé ibi tan lo
Dada la ma dé ibi tan lo
Alafia la ma mu dé ibi tan lo
Ona ma shi si gbogbo ibi ta fè lo
Ona ma han si gbogbo ibi ta ba tè
Asè ma sè si gbogbo oun ta ba sè
Iré mayo ninu gbogbo isè wa da da da da
da da da da ......
Dada la ma dé ibi tan lo
Pelu ayo la ma dé ibi tan lo
Dada la ma dé ibi tan lo
Alafia la ma mu dé ibi tan lo
Ona ma shi si gbogbo ibi ta fè lo
Ona ma han si gbogbo ibi ta ba tè
Asè ma sè si gbogbo oun ta ba sè
Iré mayo ninu gbogbo isè wa a ah
da da da da ......
Dada la ma dé ibi tan lo
Pelu ayo la ma dé ibi tan lo
Dada la ma dé ibi tan lo
Alafia la ma mu dé ibi tan lo
Ona ma shi si gbogbo ibi ta fè lo
Ona ma han si gbogbo ibi ta ba tè
Asè ma sè si gbogbo oun ta ba sè
Iré mayo ninu gbogbo isè wa a ah